Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ
This is a category for entertainment news
Meg Johnson Kú Ní Ẹni Ọdún Mẹ́rìn dín-láàdọ̀rún
Òsèré-bìnrin ọmọ ìlú gẹẹsi , Meg Johnson tó farahàn ní ìpolówó mẹ́ta to gbajúmọ̀ julo ní ìlú ọba ti jáde láyé ní ẹni ọdún Mẹ́rìn dín-láàdọ̀rún
Ebí Meg Johnson nínú àkọsílẹ kan ni wọ́n sọ pé ọ jẹ ènìyàn tó dára, tó ní iwa, ìyanu…
Rema Mú Ìyípadà Rere Bá Ìgbé Ayé Mi- Selena Gomez
Gbajú-gbajà olórin Amẹrika, Selena Gomez ti fi idunnu rẹ han si olókìkí olórin ọmọ Naijiria, Rema.
Gomez lu Rema lọ́gọ ẹnu fun ìrànlọ́wọ́ àti oore ti o se ninu aye rẹ, fun anfaani ti o fun-un lati kopa ninu orin eyi ti o…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Sàtìlẹyìn Fún Ètò Ìgbafẹ́ Ní Ìlú Lafiagi
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara, AbdulRahman AbdulRasaz sọ wípé ìjọba òun yóò se akitiyan láti jẹ́ kí ìpínlẹ̀ Kwara jẹ́ àyè ìgbafẹ́ fún àwọn ènìyàn.
Nigba ti o n sọrọ ni ilu Lafiaji, ijọba ibilẹ Edu, nibi ayẹyẹ ọdun…
Gbajúgbajà Apanilẹ́ẹ̀rín bẹnu àtẹ lu àwọn tí wọ́n ń ba àwọn alábàárìn Tinubu wí
Gbajúgbajà Apanilẹ́ẹ̀rín, Lawrence Oluwaseyitan Aletile, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Seyi Law, ti pe àwọn tí wọ́n bẹnu àtẹ́ lu àwọn ọkọ̀ alábàárìn tó tẹ̀lé ààrẹ BọlaTinubu nígbà tí ó dé ìlú Eko láti London , ní ọjọ…
Ọdún Iléyá: Portable Se Àfihàn Màálù Márùn ún, Àgbò Méjì
Akọrin ọmọ Nàìjíríà , Portable ti ṣetán láti se ọdún iléyá 2023 ní àrà ọ̀tọ̀.
Ó se àfihàn Màálù àti Àgbo tó fi owó rẹ̀ rà. Màálù márùn ún ati àgbò méjì. O sì ti ṣetán láti fífún àwọn ènìyàn lára ẹran náà pèlú ọkàn tó ń ṣoore.…
Yul Edochie Pè Fún Ìtúsílẹ̀ Nnamdi Kanu
Gbajúgbajà eléré ìtàgé, Yul Edochie ti rọ Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu láti tú Nnamdi Kanu tí ó jẹ́ adarí ajìjàgbara Biafra sílẹ̀.
Kanu, ẹni ti o ti wa ni àhámọ́ lati ọdun meji sẹ́yìn pẹlu ẹ̀sùn gbigba ominira…
Wizkid Ṣetán Láti Gbé Ọ̀tun Orin Jáde
Gbajúmọ̀ Olórin ni,Wizkid ti ṣetán láti gbé orin oní Fídíò kan jáde.
Ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù. yìí, Wizkid fi léde lórí ẹ̀rọ ayélujára pé òun yóò gbé àwo tuntun oní Fídíò jáde ní ọṣẹ to ń bọ̀.
Ó sọ èyí ní ìgbà tí ó ń se…
Olùkọrin Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Niniola Gbé Fidio Orin Tuntun Kan Jáde
Olùkọrin Afrobeats Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Niniola ti gbé Fidio orin tuntun tó pe àkọ́lé rẹ̀ ní “Gbogbo Ojú Lára Mi” tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe jáde.
“Gbogbo Oju Lára Mi” jẹ́ èkejì tó gbé jáde ní ọdún yìí. Àwọn Caltonic àti…
Burna Boy Tún Fìtàn Míràn Balẹ̀
Olùkọrin Ọmọ Nàìjíríà to ti gba àmì ẹ̀yẹ 'Grammy' , Damini Ogulu tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Burna Boy ti fi ìtàn balẹ̀ gẹgẹ bi ọmọ ilẹ̀ Adúláwọ̀ àkọ́kọ́ tí orin rẹ̀ máa jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà láti ọwọ́ ènìyàn Bílíọ̀nù kan káàkiri gbogbo…
Davido Fi Àìdùnnú Ọkàn Hàn Ní Àyájọ́ Bàbá
Gbajúgbajà olórin, David Adeleke, tí gbogbo ayé mọ̀ sí Davido ti fi àìdùnnú ọkàn hàn, tí ó sì sàpèjúwe àsìkò àyájọ́ “Bàbá” bí èyí tí ó le koko fún òun.
Akọrin náà sọ ọ̀rọ̀ náà di mímọ̀…