Browsing Category
ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ
This is a category for Africa news
Orílẹ̀-èdè Congo Kéde Ìlú-ò-fararọ Látàrí Omíyalé, Ilẹ̀ Jíjìn Tó Lágbára
Ìjọba Orílè-èdè olominira Congo ti kéde Ìlú Ò fararọ látàrí òjò àrọ̀rọ̀dá
tó ti n rọ̀ ni nǹkan bi oṣù kan ó lé.
Owó pàjáwìrì tó ju mílíọ̀nù mẹ́rin dọ́là ni ìjọba orílẹ̀-èdè náà ti gbekalẹ fún ìrànwọ́ àwọn tó lùgbàdì ọ̀ràn náà…
Ológun South Africa ní òun kò lọ́wọ́ nínú ìpinnu ọmọ Ológun kan tẹ́lẹ̀ rí tí ń dúnhuru…
Ológun orílẹ̀-èdè South African lápapọ̀ (SANDF), ti sọ pé òun kò lọ́wọ́ sí ọ̀rọ̀ tí adarí ológun kan tẹ́lẹ̀ rí, Sylvester Mangolele, ń sọ tí ó wà nínú fídíò káàkiri lórí ayélujára.
Ninu fidio naa, Ọgbẹni…
Wọ́n búra fún ọmọ Somalia-Amẹrika alákọ̀ọ́kọ́ tí wọ́n dìbò yàn ní Amẹ́ríkà
Ìgbìmọ̀ ìlú ti St. Louis Park ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, ní Minnesota ti búra fún Nadia Mohamed, tíí ṣe ọmọ ọdún mẹ́tàdín-lọ́gbọ̀n gẹ́gẹ́ bí mayor, oṣù méjì lẹ́yìn tí ó ṣẹlẹ̀ nínú ìtàn tí àwọn olùdìbò yàn ọmọ…
Ènìyàn Méjìlá Fi Ojú Ba Ilé Ẹjọ́ Látàrí Ìgbésẹ̀ Ìdìtẹ̀-gbàjọba Èyí Tí Ó Fi Orí…
Ènìyàn méjìlá ni ó ti fi ojú ba ilé ẹjọ́ ní Orílẹ̀-èdè Sierra Leone látàrí ìkópa wọn nínú ìgbésẹ̀ ìdìtẹ̀ gbàjọba èyí tí ó fi orí sánpọ́n nínú osù kọkànlá
Lára wọn ní Ọ̀gá Ọlọ́pàá tí ó ń se…
Akọròyìn Àwòrán Ọmọ South Africa Tó Gbá Ààmì Ẹyẹ Peter Magubane Kú
Peter Magubane ní akọròyìn ayàwòrán tó yá àwòrán bí wọ́n ṣé pá àwọn ènìyàn ní ipakupa ní ọdún 1960 ní Sharpeville àtí ẹjọ́ tí Nelson Mandela ní ọdún 1964.
Olúyàwòrán South Africa ló kú nì òní ọjọ́ Ajé ní ẹni ọdún ọkàn lè làádọrun (91).…
Mali: Àjọ UN fa ibùdó Timbuktu lé FAMA lọ́wọ́
Ilé iṣẹ́ UN ní Mali (MINUSMA), ti fa ìkan lára àwọn ibùdó tó ṣẹ́kù ní ìlú ńlá ní Àríwá orílẹ̀-èdè, Timbuktu ti ìjọba orílẹ̀-èdè lọ́wọ́, kí ó tó di pé ó yọwọ́ pátápátá.
Ibudo MINUSMA ni Gao ati Timbuktu…
Ààrẹ Burundi Pè Fún ìsọlókúta Pa Àwọn Ìgbéyàwó Akọ Sí Akọ Àti Abo Sí Abo
Ààrẹ Burundi, Evariste Ndayishimiye, ti pé fún ìsọlókúta pa àwọn Igbeyawo ako sí ako ati abo sí abò pe èèwọ̀ ni ati pe o burú jáì, ó fi ìdí ti ẹ̀sìn fi lòdì si hàn.
Ààrẹ náà tile ti pe tele pe kí asa náà kò kógbá wọlé ki wọn sì…
Orílẹ-èdè Egypt Gbé Ìgbésẹ̀ Akin Lójúnà Àti Fi Òpin Sí Ogun Gaza
Orílẹ̀-èdè Egypt ti gbé ìgbésẹ̀ akin láti ríi dájú pé wàhálà ogun tí ó ń wáyé láàrin Orílẹ̀-èdè Isreal ati Hamas ní Gaza di ohun àfìsẹ́yìn tí egúngún ń fi aṣọ. Ó ń réti èsì láti ọ̀dọ̀ áwọn ti ọrọ kan…
Orílẹ̀-èdè UAE Ti Parí Ọ̀rọ̀ Lórí Ìdókoòwò Tí Ó Múná Dóko Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Congo
Orílẹ̀-èdè United Arab Emirates ti parí fífi ọ̀rọ̀-jomitoro-ọ̀rọ̀ pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Congo lórí ìbásepọ̀ òwò tí ó dán mánrán, èyí tí ó jẹ́ ẹlẹ́ẹ̀kejì tí yóò wáyé pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè adúláwọ̀ láàrin ọ̀sẹ̀ kan…
Mínísítà Ilẹ̀ Òkèèrè Zambia Kọ̀wé Fí Ipò Sílẹ̀ Lórí Owó Ẹyìn
Mínísítà Ilẹ̀ Òkèèrè tí Orílẹ̀-èdè Zambia Stanley Kakubo tí kọ̀wé fí ipò sílẹ̀ látári bí wọ́n ṣé fúnra sí pé Ó owó ẹyìn lọ́wọ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè China kàn, ní ìbámu sí àwọn àlàyé látí ọdọ ilé-iṣẹ́ Ààrẹ tí orílẹ̀-èdè Áfíríkà náà.…