Browsing Category
ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ
This is a category for Africa news
Kenya Tí Ń Ṣé Àtúnṣe Sí Ède Àìyedè Tó Wà Láàrín Rẹ̀ Àti Tanzania Lórí Òfin Ọkọ̀ Òfurufú
Njẹ́ àwọn arínrín-àjò Kenya yóò ní ànfààní látí rìn ìrìn-àjò lọ́ sí Dar Es Salam, bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kejilelogun, Oṣù Kínní Ọdún yìí (22-01-2024)?
Orílẹ̀-èdè Tanzania tí kéde ní ọjọ́ kẹ́ẹdógún (15th) Oṣù Kínní pé kò sí igbalaye fún…
Ilẹ̀ Rírí Oníwakùsà Pa Méjìlélógún Ní Orílẹ̀-èdè Tanzania
Èjìlélógún ènìyàn ló ti gbẹ̀kọ je lọwọ ẹbọra látàrí ìwakùsà aláìbófinmu tó fa ilẹ̀ ríri tó wáyé ní agbègbè Àríwá Tanzania, àwọn aláṣẹ sọ èyí.
Iṣẹlẹ náà wáyé ní ibi iwakusa Ng’alita ni agbegbe Bariadi, eka Simiyu. ní ọjọ́…
Ilé Ìwé Di Títì Pa Ni Mauritius Látàrí Ìbẹrù Ìjì Líle
Àwọn ile ìwé tí di títì pa ni ìlú Mauritius látàrí àsọtẹ́lẹ̀ pé ó ṣeéṣe ki òjò tó lágbára leè rọ̀ ki ó sì fa ìkún omi.
Agbègbè French island of Réunion ni àsọtẹ́lẹ̀ ìjì líle ti leè ṣẹlẹ ni ọjọ Ajé lẹyìn idojukọ ìjì líle olókòtó ti wọ́n…
Ẹyẹ Super Eagles Kọ̀ Láti Gbéra Ní Bi Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ wọn Àkọ́kọ́ Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Equatorial Guinea Ní…
Bọọlu emi o ju ọ, iwo o jumi ni Ikọ agbabọọlu Super Eagles ti Orílẹ̀-èdè Naijiria gbá pẹlu Orílẹ̀-èdè Equatorial Guinea ni bi idije AFCON 2023 ní papa iṣere Ebimpe ní Ìlú Abidjan lorilẹde Cote d’Ivoire.
Bí wọn ṣe kọ orukọ àwọn to gba…
Omíyalé Dá Wàhálà Sílẹ̀ Ní Kinshasa, Orílẹ̀-èdè Congo
Ẹ̀kún Omi ti dá wàhálà sílẹ̀ ní Kinshasa, olú ìlú DR Congo nígbà tí ẹ̀kún omi gba-ilé, gba-oko tí ó sì ba ọ̀pọ̀lọpọ̀ dúkìá jẹ́
Ìròyìn fi yéwa pé ọ̀ọ́dúnrún ènìyàn ni ó pàdánù ẹ̀mí látàrí…
Àjọ WHO Kéde Cape Verde Gẹ́gẹ́ Bí Èyí Tí Ó Peregedé Lọ́wọ́ Àìsàn Ibà
Àjọ elétò ìlera àgbáyé (WHO) ti kéde Orílẹ̀-èdè Cape Verde gẹ́gẹ́ bí èyí ti o peregedé kúrò lọ́wọ́ àìsàn ibà
Àyẹ̀wò wáyé ní erékùsù ìwọ oòrùn Afirika mẹ́sàn-án èyí tí àjọ náà kéde ní…
AFCON Ọdún 2023: Agbábọ̀ọ̀lù Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà Iheanacho Àti Moffi Yóò Darapọ̀ Mọ́…
Agbábọ̀ọ̀lù Iwájú fún Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà Kelechi Iheanacho àti Terem Moffi yóò lọ darapọ mọ àwọn agbábọ̀ọ̀lù yòókù fún ife bọọlu Afirika (AFCON) ti ọdun 2023 ti yóò waye ní Orílẹ̀-èdè Cote d’Ivoire ní ọjọ́…
Pistorius Eléré-Ìje Ọmọ South Africa Gbá Ìtusílẹ̀
Eléré-ìje ọmọ Orílẹ̀-èdè South Africa Oscar Pistorius tí gbá ìtusílẹ̀ látí túbú pẹ̀lú afòríjì lẹyìn tó tí wà ní àhámọ́ ní ọdún mẹ́sàn fún pípa ọrẹbinrin rẹ̀ àtí pé ó tí wà ní ìlé ní báyìí, Ẹ̀ka Àtúnṣe tí Orílẹ̀-èdè South Africa sọ.…
Ìjàmbá Ọkọ̀ Ogun Òfurufú Pa Ènìyàn Méjì
Ọkọ̀ Ogun Ofurufu fi orí sọ ilé ìgbé ni agbègbè ìwọ̀ oòrùn Ntoroko, orílẹ̀-èdè Uganda, ó sì polúkúmusu.
Iṣẹlẹ náà wáyé ni àlà pẹ̀lú ẹ̀gbẹ́ orílẹ̀-èdè olominira Congo to sì pa gbogbo awọn eniyan to wa ninu rẹ àti ènìyàn to wa…
Orílẹ̀-èdè Congo Kéde Ìlú-ò-fararọ Látàrí Omíyalé, Ilẹ̀ Jíjìn Tó Lágbára
Ìjọba Orílè-èdè olominira Congo ti kéde Ìlú Ò fararọ látàrí òjò àrọ̀rọ̀dá
tó ti n rọ̀ ni nǹkan bi oṣù kan ó lé.
Owó pàjáwìrì tó ju mílíọ̀nù mẹ́rin dọ́là ni ìjọba orílẹ̀-èdè náà ti gbekalẹ fún ìrànwọ́ àwọn tó lùgbàdì ọ̀ràn náà…