Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ

This is a category for Africa news

Àwọn Méjì Pàdánù Ẹmí Wọ́n Nínú Ìjàmbá Ọkọ̀ Òfurufú Ní Kenya

Ènìyàn méjì ní ìròyìn ṣàfihàn pé ó kú nínú ìjàmbá ọkọ̀ Òfurufú kàn, láàrín ọkọ̀ òfurufú akẹ́kọ̀ọ́ kàn àtí ọkọ̀ òfurufú akérò kàn ní Olú-ìlú Kenya ní Nairobi, àwọn ọlọ́pàá àgbègbè náà sọ ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun. Ìṣẹlẹ̀ náà wáyé ní aago mẹ́wàá…

Orílẹ̀-èdè Zimbabwe: Ìròyìn Ìdẹ́rùbà Àdó Olóró Mu Kí Ààrẹ Wọ Gile Ìrìn Àjò Rẹ 

Látàrí Ìdẹ́rùbà àdó olòrò, to mú kí pápákọ̀ òfurufú Victoria Fall dáwọ iṣé dúró ní ọjọ́ ẹtì, èyí ló ṣe okun fa ti Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Zimbabwe náà wọ Gile Ìrìn Àjò rẹ lo sí bí ìpàdé ti yóò ti bawon sọ̀rọ̀. Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Zimbabwe Edson…

Orílẹ̀-èdè Algeria Se Ìfilọ́lẹ̀ Mọ́sálásí Tí Ó Tóbi Jùlọ Ní Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Lẹ́yìn…

Algeria se ìfilọ́lẹ̀ Mọ́sálásí ńlá kan èyí tí ó wáyé lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpènijà   Àwọn agbaṣẹ́se Orílẹ̀-èdè China ni ìròyìn fi yéwa pé ó se iṣẹ́ náà. Mọ́sálásí Algeria náà ni ó jẹ́ èyí tí òsóóró…

Orílẹ̀-èdè Burkina Faso: Àwọn Mẹẹdogun Ló Jáde Láyè Látàrí Ikọlu To Wáyé Ní ilé Ìjọsìn Catholic.

Ó kéré jù ènìyàn mẹ́ẹ̀dógún ló jẹ́ Ọlọ́run nipé nígbà tí àwọn àgbẹbọ kọlu ilé ìjósìn lakọkọ ti wọn jọsin lọ́wọ́ Ìròyìn ní lójú ẹsẹ̀ ni àwọn méjìlá jáde láyè nígbà tí àwọn tó kún náà padà jáde láyè lásìkò ti wọn n toju wọn Gẹ́gẹ́ bí…
button