Àìsàn Ebola Tàn Kálẹ̀ Ní Ìlú Uganda
Àìsàn Ebola ti tàn kálẹ̀ síi ní ìlú Uganda, tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì ti fi ara káásá àrùn náà, léyìí tí kò dín ní èèyàn métàlélógún sì ti gba èkuru jẹ lọ́wọ́ ẹbọra. Àjọ elétò ìlera ni ó fi ọ̀rọ̀ náà léde…