Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra Gbé Ìgbésẹ̀ Akin Lójúnà Síse Àtúnse Ojú Pópó

0 54

Gómínà Chukuma Charles Soludo ti se àbẹ̀wò sí ilé isẹ́ tí ó ń rí sí àtúnse òpópónà ti ìjọba àpapọ̀ ní ìlú Àbújá láti se àmúgbòòrò àtúnse ojú ọ̀nà ìpínlẹ̀ náà.

 

Gómìnà, ẹni tí onímọ̀ ẹ̀rọ Rafindadi gba àlejò rẹ̀ gbé oríyìn fún àjọ náà nípa ìlàkààkà rẹ̀ láti se àtúnse àwọn ojú pópó wa àti àmójútó wọn.

 

Ó pèpè fún ìbásepọ̀ tí ó dán mánrán fún síse àtúnse àwọn òpópónà ìpínlẹ̀ rẹ̀. Ó sì se àdéhùn pé, ìfilọ́lẹ̀ àtúnse ọ̀nà yóò gbéra sọ ní ìpínlẹ̀ Anambra ní ọ̀pọ̀ yanturu.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.