Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Ọmọ Ogun Gún Àwọn Onìròyìn Ní Kẹ́sẹ́ Fún Ìfiléde Àwọn Ìròyìn lórí Àseyọrí Wọn.

Wọ́n ti rọ àwọn akọ̀ròyìn jákè-jádò orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fún ìfiléde ìròyìn lórí àseyọrí àwọn ọmọ ogun àti ipa ribiribi tí wọn ńkó lójúnà àti pèsè ààbò tí ó péye, kí wọ́n sì gbógun ti àwọn ọ̀tá…
button