Take a fresh look at your lifestyle.

Akọ̀wé Ilé Ìṣúra Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, Yellen Bẹ Orílẹ̀-èdè Sẹ́nẹ́ga Wo

Akọ̀wé Ilé Ìṣura Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, Janet Yellen bẹ ilé aláwọ̀ píńkìì ní ìkọjá erékùṣù ti Orílẹ̀-èdè Sẹ́nẹ́ga Wo. Ìbẹ̀wò Yellen jẹ́ ara ìbẹ̀wò ọlọ́jọ́ mẹ́wàá pẹ̀lú èròngbà láti tù àjọṣepọ̀ ọrọ̀ ajé tó wà láàárín ilẹ̀ Amẹ́ríkà…

Àjọ Continental Reinsurance Organisation Ṣetán Láti Fi Àmì Ẹ̀yẹ Dà Oníròyìn To Dàgánjíá Lọ́lá

Àjọ ‘Continental Reinsurance Plc’ ti pe àwọn oníròyìn jákèjádò láti ṣe àgbékalẹ̀ iṣẹ́ wọn fún idanilola àmì ẹ̀yẹ ti àwọn oníròyìn ti ọdún 2023. Wọ́n pe ìpè yí láti bù ọlá fún àwọn oníròyìn tó peregedé ní àwùjọ Oníròyìn. Àjọ…

Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Nottingham Forest Tẹwọ́ Bọ Ìwé Àdéhùn Pẹ̀lú Agbábọ́ọ̀lù Ilẹ̀ Brazil Kan

Ẹgbẹ Agbábọ́ọ̀lù Nottingham Forest ti lọ tẹwọ́ bọ ìwé àdéhùn pẹ̀lú agbábọ́ọ̀lù Ilẹ̀ Brazil Kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Danilo. Danilo tó wá láti inú ẹgbẹ́ agbábọ́ölù Palmeiras, yóò sì gba bọ́ọ̀lù títí di ọdún 2029 pẹ̀lú wọn bí ẹgbẹ́…

Igbákejì Ààrẹ, Òsínbàjò Darí Ìpàdé Àwọn Mínísítà Alákọ́kọ́ Ti Ọdún 2023

Ìpàdé alákọkọ́ ti àwọn Mínísítà ti Ọdún 2023 ti orílẹ̀-èdè yìí ni à ń darí rẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ láti ọwọ́ Igbákejì ààrẹ Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Òsínbàjò, ní ilé ìgbìmọ̀ ìpàdé ti ààrẹ ní Àbújá. Gbogbo àwọn Mínísítà ló péjú pèsẹ̀ eléyìí…
button