Ènìyàn Pàtàkì, Ọmọ Bíbí Ìpínlẹ̀ Bauchi Yóò Jẹ Anfààní Ìlera Ọ̀fẹ
Àjọ Bauchi State Health Contributory Management Agency, BASHCMA, sọ pé àwọn tí kọ orúkọ àwọn ènìyàn pàtàkì, ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Bauchi ti yóò jẹ ànfààní Ìlera ọ̀fẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tí yóò jẹ ànfààní yi ní wọ́n sà kà kiri…