Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Aláṣẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Fọwọ́sí Ìdáàbòbò Àwọn Ọmọdé Lórí Ayélujára

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti bú ọwọ́ lú ìwé àṣẹ àti ìlànà ìdáàbòbò àwọn ọmọdé lórí ayélujára lọ́wọ́ àwọn òun èlò ayélujára tó lé ní ipá lórí ayé wọ́n. Ìlànà náà ní wọ́n fọwọ́sí ní Ọjọ́bọ̀ ní ìpàdé tí Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ tí Ìjọba Àpapọ̀ tí…

Ọgá Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Borno Pín Àwọn Ọlọ́pàá Káàkiri Ìpínlẹ̀ Náà

Ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Borno ní ọjọ́ Ẹtì, sọ́ pé àwọn yóò pín ọlọ́pàá tó ṣẹ̀ṣẹ̀ gbokun láti Kọlẹẹjì, ẹgbẹ̀rin àtí méjìdínlógún sì gbogbo ìjọba ìbílẹ̀ láti kún àwọn ẹṣọ ààbò fún ètò ìdìbò gbogbogbòò 2023. Ẹ tun lè kà nípa: Ọlọ́pàá…

Ààrẹ Buhari Yóò Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Àwọn Ìṣẹ́ Àkànṣe Ní Ìpínlẹ̀ Èkó

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ní ọjọ́ Ẹtì sọ pé Ààrẹ Muhammadu Buhari yóò ṣé ìfilọ́lẹ̀ àwọn iṣẹ́ àkànṣe márùn ní ìpínlẹ̀ náà láti ọjọ́ kẹta-lé-lógún (23) sí ọjọ́ kẹ̀rin-lé-lógún (24) Oṣù Kínní ọdún yìí. Komisana fún Ìròyìn àtí Ìlànà, Ọ̀gbẹ́ni…

Ọlọ́pàá Nàìjíríà Pín Òwò Fún Ìdílé Àwọn Ọlọ́pàá Tó Pàdánù Ẹ̀mí Wọ́n Lẹ́nù Ìṣẹ́

Ọlọ́pàá Nàìjíríà sọ pé òun tí bẹ̀rẹ̀ pínpín ìwé sọwedowo fún àwọn òṣìṣẹ́ òún tó pàdánù ẹ̀mí wọ́n làkókò tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ sìn ìlú Bàbá wọ́n àti àwọn tó ní ìfárapá èyí tó sọ wọ́n dí aláàbọ̀ àrá lẹ́nù ìṣẹ́. Ọgá àgbà fún Ọlọ́pàá IGP Usman…
button