Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ní ọjọ́ Ẹtì sọ pé Ààrẹ Muhammadu Buhari yóò ṣé ìfilọ́lẹ̀ àwọn iṣẹ́ àkànṣe márùn ní ìpínlẹ̀ náà láti ọjọ́ kẹta-lé-lógún (23) sí ọjọ́ kẹ̀rin-lé-lógún (24) Oṣù Kínní ọdún yìí.
Komisana fún Ìròyìn àtí Ìlànà, Ọ̀gbẹ́ni Gbenga Omotoso sọ èyí dì mímọ̀ ní Ikeja, Olú ìlú ìpínlẹ̀ Èkó, làkókò àpéjọpọ̀ àwọn òníròyìn tí a fí sami sí: “Ayẹyẹ tí Ìgbìmọ̀ Iṣẹ́ àkànṣe.”
Omotoso ṣàlàyé pé àwọn iṣẹ́ àkànṣe márùn ùn ní Ààrẹ yóò ṣé ìfilọ́lẹ̀ rẹ̀ ní.
Tún kà nípa: Ìpínlẹ̀ Èkó Ṣègbékalẹ̀ Ètò Ìmúgbòòrò Sí Àwọn Ilé Ìtọjú Ìlera Alàkọ́bẹ̀rẹ̀
* Ìbùdó Òkun Lekki (Àjọṣepọ̀ ìjọba àtí Aladani)
* 32-metric tọ́ọ̀nù wákàtí kàn, Lagos Rice Mill, Imota
* 18.75-kilomita opopona onilá mẹ́fà tó lagbara Eleko Junction sí Epe Expressway
* John Randle, Ile-iṣẹ àṣà àti ìtàn Yorùbá
* Reluwee Èkó tuntun (Lagos Blue Rail)
Àti
* Ilé-iṣẹ́ èpò MRS, Apapa (Aladani)
Lekan Orenuga
[…] Tún kà nípa: Ààrẹ Buhari Yóò Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Àwọn Ìṣẹ́ Àkànṣe Ní Ìpínlẹ̀ Èkó […]
Àtí gbaradi látí kí Ààrẹ káàbọ̀ sí Imota “Atayo”