Àwọn àwakùsà góòlù pàdánù ẹ̀mí ènìyàn mẹ́ta ní ìgbà tí adó ìwakùsà bú ní àpá ìwọ̀ òòrùn ní Orílẹ̀-èdè Kenya.
Ilé iṣẹ́ ìwakùsà góòlù tí Karebe (Kerebe gold mining company) sọ pé ògiri kan tí wọ́n mọ́ láti dènà Omí yalé ní agbègbè náà ní adó ìwakùsà àwon àwakùsà lọ́nà tí kò bá òfin mú kọlù tó sì gbà ẹ̀mí àwọn òṣìṣẹ́ mẹ́ta tí àwọn mẹ́ta mìíràn sí fí àràpà, ṣùgbọ́n ilé ìwòsàn dá wọ́n sílẹ̀ lẹyìn ìtọjú.
Ile-iṣẹ náà sọ pé òṣìṣẹ́ ìjọba kàn tí ṣé àbẹwò sí àgbègbè ìwakùsà náà ní ọjọ́ Ajé, Ó sí pàṣẹ fún àwọn àwakùsà àrúfin wọ́nyi láti dá iṣẹ́ wọ́n dúró.
Ìṣẹ̀lẹ̀ adó yìí jẹ́ òun àjòjì ní Orílẹ̀-èdè Kenya.
Karebe sọ pé àwọn tí kàn sí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ látí ọdún 2021 láti dá sí kí wọ́n sì dà àwọn àwakùsà lọ́nà àìtọ́ l’ẹkun ní agbègbè ìwé àṣẹ rẹ̀.
Lekan Orenuga
Ẹ jẹ́ a dẹkùn ìwakùsà àwon òun alumọni ilẹ Áfíríkà lọ́nà àìtọ́