Ọlọ́pàá Nàìjíríà sọ pé òun tí bẹ̀rẹ̀ pínpín ìwé sọwedowo fún àwọn òṣìṣẹ́ òún tó pàdánù ẹ̀mí wọ́n làkókò tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ sìn ìlú Bàbá wọ́n àti àwọn tó ní ìfárapá èyí tó sọ wọ́n dí aláàbọ̀ àrá lẹ́nù ìṣẹ́.
Ọgá àgbà fún Ọlọ́pàá IGP Usman Alkali ló sọ èyí dì mímọ̀ làkókò tó ń pín àpapọ̀ ìyè òwò bílíọ̀nù mẹtala Náírà tí wọ́n fún ẹgbẹ̀rún méje ìdílé tí àwọn òṣìṣẹ́ wọ́n tó kú àtí àwọn tó f’arapa tàbí tí wọ́n dì aláàbọ̀ àrá lẹ́nù iṣẹ́ wọ́n láàrín ọdún 2012 sí 2020.
Tún kà nípa: Ọgá Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Borno Pín Àwọn Ọlọ́pàá Káàkiri Ìpínlẹ̀ Náà
O tún ṣé ìlérí àwọn ìrànlọ́wọ́ òún mère mère fún àwọn ìdílé àti ẹ̀bi ọlọ́pàá bóyá tí ń ṣiṣẹ́ lọ̀wọ̀, fẹ́yìn tí, tàbí tí wọ́n pà lẹ́nù iṣẹ́ látí lé fí ìsọkan rínlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọrọ̀ wọ́n tó ní “esprit de Corps” láàrín àwọn òun èlò ìdílé ọlọ́pàá.
Lekan Orenuga
[…] Ẹ tun lè kà nípa: Ọlọ́pàá Nàìjíríà Pín Òwò Fún Ìdílé Àwọn Ọlọ́pàá Tó Pàdánù Ẹ̀mí … […]
Ẹ ṣeun, iṣẹ́ ìlú ń tèsíwájú. Ẹ kú ìṣẹ́