Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ-èdè Nàìjíríà Gbero Làti Pa Ìyè Owo Ti O To Ẹdẹgbẹta Bílíọ̀nù Náírà (N500b) Ni Ọdun 2023

Ìgbìmọ̀ Ibaraẹnisọrọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, NCC ti ṣe àfihàn ètò rẹ̀ láti ṣé ipilẹṣẹ tó jù ẹdẹgbẹta biliọnu náírà (N500b) ní ọdún 2023 nípasẹ 5G spectrum. Igbákejì Alága Alase tí NCC, Ọjọgbọn Umar Danbatta, fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ ni Abùjá,…

Àárẹ̀ Nàìjíríà Ṣe ìlérí Láti Tẹ Síwájú Nínú ìfọ̀rọ̀wérọ̀ Lórí Àwọn Ìbéèrè Àjọ Olukọni Ìlé-ẹkó Gíga

Ààrẹ Muhammadu Buhari tí ṣé ìlérí láti ṣé ìtẹ̀síwájú lórí ìfọrọwanilẹnuwo pẹ̀lú àwọn tó níí ṣé ní étò ẹ̀kọ́, làti wà òpin sí rògbòdìyàn ẹgbẹ àwọn olukọni ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Academic Staff Union of Universities (ASUU). O ṣé ìlérí náà ní…

Ìjọba Nàìjíríà Sanwó Ìtanràn Fún Àwọn ènìyàn Mẹ́rìnléláàdọ́rin Tí Àwọn Ọlọ́pàá Fí Ìyà Àìtọ́…

Ìjọba Nàìjíríà tí sàn owo tó jù igba o le mejidinlọgọrin miliọnu naira (289m) fun àwọn mẹrinlelaadọrin (74) lórí bí wọn se tẹ ẹtọ  ọmọniyan  loju mọlẹ ati ẹsun iwa ọdaju tí  awọn ọlọ́pàá kàn hu si wọn . Ìgbìmọ̀ Ìwádìí olómìnira lórí…
button