Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Orílè-èdè South Africa Gbéra Lọ́ Sí Orílẹ-èdè Amẹ́ríkà

0 101

Ààrẹ South Africa Cyril Ramaphosa gbera lọ si Washington lati pade pẹlu Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Awọn akọroyin jabọ pé yóò ṣé ìpàdé pẹ̀lú Ààrẹ Amẹ́ríkà Joe Biden ni olú-ìlú náà ni Ọjọ Kerindinlogun Oṣù Kẹsan ọdún, 2022.

Yóò sì tún pàdé Igbakeji-Aare Amẹ́ríkà ìyẹn Kamala Harris ni ọfiisi rẹ.

Ìpàdé àti ijiroro náà yóò dá lórí, itẹsiwaju àlàáfíà lágbayé, ìṣòwò, ijiroro lori awọn ìlé-íṣẹ́ lágbayé ati lori Àjọ Àgbáyé (United Nations)

Lekan Orenuga

Leave A Reply

Your email address will not be published.