Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí gúnlẹ̀ sí pápákọ̀ òfurufú àgbáyé ìpínlẹ̀ Enúgu

Ààrẹ orílè-èdè Nàìjíríà, Mòhámmádù Bùhárí ti dé sí Pápákọ̀ òfurufú àgbáyé Akanu Ibiam ní Enugu fún iṣẹ́ àbẹ̀wò  ọlọ́jọ́ méjì ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi ní Gúúsù ilà oòrùn Nàìjíríà. Oludamọran ofin…

A kò rà mọ́

Orílẹ̀-èdè Taiwan ti sọ  ní ọjọ́bọ̀ pé òun kò rà àwọn bàálù kékeré  ìjagun abẹ́lẹ̀-omi láti Amẹ́ríkà mọ́,wípé ó ti wọ́n jù. Taiwan ti sọ tẹlẹ pe o n gbero lati ra awọn ọkọ ofurufu abelẹ-omi 12 MH-60R, ti Lockheed…

EU gbẹ́sẹ̀lé Epo orílè-èdè Rọ́síà Àti Àwọn ilé-iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Mẹ́ta

Àjọ ìṣọ̀kan yúróópù EU yóò gbẹ́sẹ̀lé gbígbéwọlé epo orílẹ̀-èdè Rọ́ssíà, àwọn ọjà tí wọ́n túnṣe àti àwọn olùgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ti ìjọba orílẹ̀-èdè Rọ́síà mẹ́ta gẹ́gẹ́ bí apákan ìdíi ìjẹniníyà kẹfà lórí…

Al-Shabaab sọ pé òun ló wà nídìí ìkọlù apànìyàn tó ṣẹlẹ̀ ní Ibùdó AU ní Sòmálíà

Àwọn ajagun Al-Shabaab ti yabo ilé-iṣẹ́ ìṣọ̀kan Áfíríkà kan ní Sòmálíà pẹ̀lú ìbọn àti ibẹjadi ní ọjọ́ ìṣégun,ní èyí  tí ó fa ìyìnbọn lura tí ó pa àwọn olùpèsè alààfíà Burundi. Ọgágun ọmọ ogun Burundi…
button