Take a fresh look at your lifestyle.

Ibà Lassa: Onísègùn ń pè fún àfikún Àwọn olùyẹ̀wò Ìlera Àyíká

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 37

Onísègùn ìlera tìjọba, Ọ̀jọ̀gbọ́n Tanímọ̀la Àkàndé, ti rọ  ìjọba ní gbogbo ìpele láti gba àwọn olùyẹ̀wò ìlera àyíká kún àwọn tó wà nílẹ̀ lọ́wọ́  láti dín ìtànkálẹ̀ àrùn ibà Lassa kù láwùjọ.

Aarẹ nigbakan ri,fun Ẹgbẹ Awọn Onisegun Ilera Awujọ,Akande, ṣe ipe yii lakoko ifọrọwanilẹnuwo pẹlu awọn oniroyin ni ọjọ iṣẹgun, ni Ilu Eko.

Gege bi o ti sọ, iṣẹlẹ  iba Lassa ni ọpọlọpọ awọn ipinlẹ jẹ nnkan to n kọni lominu ati pe agbajọ ọwọ lafii sọya lati din  aisan naa ku.

Akanni sọ pe,Aigbanisiṣẹ ijọba ni o fa aini  awọn oṣiṣẹ ilera toto,o pe  akiyesi si pe awọn oṣiṣẹ ilera ayika kere si  awọn olugbe orilẹ-ede.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.