Ibà Lassa: Onísègùn ń pè fún àfikún Àwọn olùyẹ̀wò Ìlera Àyíká
Onísègùn ìlera tìjọba, Ọ̀jọ̀gbọ́n Tanímọ̀la Àkàndé, ti rọ ìjọba ní gbogbo ìpele láti gba àwọn olùyẹ̀wò ìlera àyíká kún àwọn tó wà nílẹ̀ lọ́wọ́ láti dín ìtànkálẹ̀ àrùn ibà Lassa kù láwùjọ.
Aarẹ…