Ilẹ̀-Rúrú Pa O Kéré Tán Ènìyàn Méjìlélógún Ní Nepal
Látàrí Òjó àrọtúnrọ tí ó rọ ní Ìwọ-Oòrùn Nepal, Ilẹ̀-Rúrú gba ẹ̀mí ènìyàn méjìlélógún, nígbà tí àwọn mẹ́wàá sì Fárápa.
Àwọn ìkọ Ádólà Ẹ̀mí sá gbogbo ipá wọ́n láti kó àwọn tí Ilẹ̀-Rúrú tí sìn láyé kúrò. Agbẹnusọ àwọn Ọlọ́pàá, Dan…