Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Zambia Jáwe Gbélé Ẹ Fún Ìgbà Diẹ Fún Olórí Afẹ̀sùnkànní

0 303

 

Ààrẹ Zambia, Hakainde Hichilema jáwe gbélé Ẹ lẹsẹ́ kẹsẹ́ fún Olórí Afẹ̀sùnkànní tí Ipinlẹ.  Ìkéde yìí wáyé lẹ́yìn  bí ọjọ́ méjì tí ó kéde wí pé àyè ohùn wà nínú èwù.

 

Ààrẹ àná ní O yàn Lillian Siyunyi sii ipò, o sì n bá ìjọba àná lọ, ẹ̀sùn tì pọju nípa bí kò ṣe ṣe iṣẹ́ rẹ dójú àmín ní ile-ẹjọ Igbimọ Ẹdun Idajọ (JJC).  Kí ìdá dúró yí tó wáyé ní ìjọba ìpínlẹ́ tí yọ àwọn Ẹṣọ Alaabo tí ó ń ṣọ.

 

Agbẹnusọ Ààrẹ, Anthony Bwalya sọ pé àṣẹ yìí wáyé lẹ́yìn àfisún ati abá Olórí Igbimọ Ẹdun Idajọ – JJC.  O ní, Katongo Waluzimba ní wọn yàn gẹgẹ bí Adele Olórí Afẹ̀sùnkànní

 

Ms. Siyunyi nígbà tí ó fi Ẹhonu rẹ hàn sọ pe “mó ní ohùn pupọ làtì sọ” ní kété tí Ààrẹ bá tí yàndá ànfààní àṣírí ìbúra fún ó hùn.

 

“Àǹfààní yìí ni yóò fún mí ní  Oore-Ọfẹ làti sọ tẹnù mí la láàfia láìsí ẹrù làti ọdọ ẹnì kẹni tàbi ìpín kánkán,” èyí níí ọ̀rọ̀ láti ẹnu Arábìnrin yìí. Òní tí Ohùn ba farahàn níwájú JJC ki wọn to fun ohùn ni àṣẹ àti ànfààní yìí, pé ó lòdì sí Òfin.

 

Olubunmi Adeyẹmọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button