Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Ajọ Yúrópù (European Union, EU) tí ṣé ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí ọrọ̀-ajé gẹ́gẹ́ bí ará àwọn akitiyan láti ṣé àtìlẹ́yìn ìyípadà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lórí ètò ọrọ̀-àjé.

Èyí yóò ṣé ìrànlọ́wọ́ fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti pèsè iṣẹ́ àtí láti yanjú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn rògbòdìyàn tó nlọ lọ́wọ́ àtí ìyípadà ojú-ọjọ́.


Akọ̀wé àgbà tí ilé-iṣé ètò àyíká tí ìjọba àpapọ̀ (Federal Ministry of Environment), Ọ̀gbẹ́ni Ibhraim Yusufu sọ èyí ní ìdánilẹ́kọ̀ọ́ tí orílẹ̀-èdè ọlọjọ kàn ti “Nigeria Circular Economy Roadmap” tó wáyé ní Abuja, olú-ìlú orílẹ̀-èdè náà.

Ilé-iṣẹ́ ìjọba tí Àyíká ní Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn tó níí ṣé pàtàkì sí Ètò Ìṣòwò Ìlú Nàìjíríà ṣé ìfilọ́lẹ̀ “Nigeria Circular Economy Program” gẹ́gẹ́ bí akitiyan láti ṣé ìdàgbàsókè àwọn ẹ̀ka kàn
Leave a Reply