Igbákejì ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kashim Shettima ń darí ìpàdé àpérò lórí ètò ọrọ̀ ajé
Ìpàdé náà ń lọ lọ́wọ́, èyí tí àwọn gómìnà mẹ́rìndínlógójì péjú síbẹ̀.
Ìpàdé náà máa ń wáyé ní osoòsù, láti wá ojútùú sí ìsòro ọrọ̀ ajé tí kò ra jaja.
Leave a Reply