Ìgbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kashim Shettima, tí ṣé àfihàn ìdúróṣinṣin òún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan pàtàkì nínú ètò-ọrọ àjé tí ìṣàkóso Ààrẹ Tinubu fún ọdún 2024.
Èyí jẹ́ gẹ́gẹ́ bí Ìgbìmọ̀ ètò-ọrọ àjé orílẹ̀-èdè (NEC) ṣé tí rawọ ẹbẹ sí Ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ (NLC) láti bẹ́ ìgi di iyanṣẹlodi tí wọ́n pinnu, Ó sọ pé “Ààrẹ Bola Tinubu ṣetán láti ṣé ìrànwọ́ fún àwọn òṣìṣẹ́ Nàìjíríà.”
Ìgbákejì Ààrẹ sọ pé àwọn tó wà ní ìjọba àpapọ̀, ìpínlẹ̀, àti àwọn ìjọba ìbílẹ̀ gbọ́dọ̀ ṣé akitiyan láti ṣé àyẹwò àwọn òun pàtàkì, ìlànà àtúnṣe àti ìdáàbòbò àwùjọ, idoko-owo àti oúnjẹ.
Shettima sọ èyí ní Ọjọ́bọ̀ ní ìpàdé tí National Economic Council (NEC) tó wáyé ní Ilé-ìgbìmọ̀ tí Ààrẹ ní, Abuja.
Leave a Reply