Take a fresh look at your lifestyle.

NYSC Ṣètò Ìlọsíwájú Àlàáfíà Fún Àwọn Ọmọ Ẹgbẹ́ Àgùnbánirọ̀

0 284

National Youth Service Corps NYSC, tí ṣètò ikẹkọ ọlọjọ kàn fún àwọn òṣìṣẹ́ àtí ọmọ ẹgbẹ́ láti mú ìlọsíwájú bá wọ́n.

Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ náà wáyé ní Abakaliki, ní Gúúsù ìlà oòrùn Nàìjíríà.

Èyí wáyé nínú adirẹsi tí Olùdarí Gbogbogbò NYSC, Yusha’u Ahmed gbé kalẹ̀ lákókó ikẹkọ náà.

Olùdarí Àgbà náà tí ìgbákejì Olùdarí àgbà gúúsù ìlà oòrùn ṣé ojú rẹ̀, Iyaafin Mary Chikezie, sọ pé èyí yóò ṣé ìdánilójú iṣẹ́ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àgùnbánirọ̀ dáradára, yóò tún ṣé ìlọsíwájú ní àwọn ààyè kàn. Nitorinaa, èyí yóò yọrí sí ìdàgbàsókè eto-ọrọ àjé tí orílẹ̀-èdè.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button