Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Ní Yóó Ṣé Òkùnfà Ìdàgbàsókè Ìṣòwò Orílẹ̀-èdè Yíì – Ìgbákejì Ààrẹ Nàìjíríà
Ìgbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kashim Shettima, tí ṣé àfihàn ìdúróṣinṣin òún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan pàtàkì nínú ètò-ọrọ àjé tí ìṣàkóso Ààrẹ Tinubu fún ọdún 2024.
Èyí jẹ́ gẹ́gẹ́ bí Ìgbìmọ̀ ètò-ọrọ àjé orílẹ̀-èdè (NEC) ṣé tí…