Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà Gbá Ife Ẹ̀yẹ Bọ́ọ̀lù Afọ́wọ́-Jù-Sápẹ̀rẹ̀ Ní Áfíríkà

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 397

D’Tigress tí Nàìjíríà tí gbá ìfé ẹ̀yẹ 2023 FIBA Afrobasket tí àwọn Obìnrin fún ìgbà kẹrin leralera pẹ̀lú bí wọ́n ṣé fàgbà hàn Senegal ní àmì mẹ́rinlèlọgọ́rin sí mẹ́rinlèlàádọ́rin 84-74.

Nàìjíríà tí dì ìkọ kejì lẹ́yìn Senegal láti gbà ife ẹ̀yẹ mẹ́rin leralera

Olukọni D’Tigress Rena Wakama, ẹnití o jẹ́ olukọni Obìnrin kàn ṣoṣo ní 2023 FIBA ​​Women’s AfroBasket, ní báyìí ní olukọni Obìnrin àkọ́kọ́ látí gbá ife náà nígbà àkọ́kọ́ rẹ̀ pẹ̀lú Nàìjíríà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button