Nàìjíríà Gbá Ife Ẹ̀yẹ Bọ́ọ̀lù Afọ́wọ́-Jù-Sápẹ̀rẹ̀ Ní Áfíríkà
D'Tigress tí Nàìjíríà tí gbá ìfé ẹ̀yẹ 2023 FIBA Afrobasket tí àwọn Obìnrin fún ìgbà kẹrin leralera pẹ̀lú bí wọ́n ṣé fàgbà hàn Senegal ní àmì mẹ́rinlèlọgọ́rin sí mẹ́rinlèlàádọ́rin 84-74.
Nàìjíríà tí dì ìkọ kejì lẹ́yìn Senegal láti gbà…