Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano tí ṣé ìkìlọ pé òún kó ní lọrá látí fá ìgi lé àwọn ìwé-àṣẹ tí àwọn oníṣòwò pàtàkì tàbí gbé ìgbésẹ lórí ẹnikẹni tó kọ̀ látí gbà àwọn òwò náírà àtijọ.
Gómìnà Abdullahi Umar Ganduje tó fí ìkìlọ náà lélẹ̀ nínú àtẹ̀jáde kán tí Kọmisana fún ètò ìròyìn àtí ọrọ abẹ́lé, Malam Muhammad Garba, fí síta, sọ pé àwọn òwò náírà àtijọ náà sí jẹ́ òun itẹwọgbà lábẹ́ òfin.
Ó sọ pé ilé-ẹjọ́ gíga tí pàṣẹ pé kí á sí máa ná owó náírà àtijọ náà lọ́ títí tí yóò fí kúrò nílùú.
Gómìnà woyé pé àwọn oníṣòwò gẹ́gẹ́ bí àwọn ilé ìtàjà, bánkì, ilé èpò, ilé oúnjẹ, ilé ìtura, ìbùdó-kọ̀ àtí bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ́ tí ń dá àṣà látí kọ́ owó náírà àtijọ sílẹ̀.
Gómìnà náà ké sí àwọn aráàlú ìpínlẹ̀ náà látí tèsíwájú níbí nínà òwò àtijọ náà, kí wọ́n sì fí tó àwọn agbofinro létí, ẹnikẹni tó bá kọ́ látí gbà owó náírà àtijọ.
Lekan Orenuga
Leave a Reply