Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

CBN

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kaduna Tí Kìlọ Fún Àwọn Aráàlú Látí Yàgò Fún Irúfìn

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kaduna sọ pé àwọn tí gbá áwọn ìjàbọ̀ lórí àwọn ẹgbẹ́ aráàlú kàn tó ń gbèrò láti ṣé ìwọdé lójú òpópó-ònà tó lé kóbá àlàáfíà àti ètò ìlú. Nítorí náà ìjọ̀ba tí gbà àwọn aráàlú níyànjú láti yàgò fún irúfẹ́ bẹ́ẹ̀, ó sí kílọ…

Ilé ifowopamọ, Àwọn Onísòwò Tó Bá Kọ́ Owó Àtíjọ́ Yóò Jẹ̀ Iyán Rẹ̀ Níṣú – Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano tí ṣé ìkìlọ pé òún kó ní lọrá látí fá ìgi lé àwọn ìwé-àṣẹ tí àwọn oníṣòwò pàtàkì tàbí gbé ìgbésẹ lórí ẹnikẹni tó kọ̀ látí gbà àwọn òwò náírà àtijọ. Gómìnà Abdullahi Umar Ganduje tó fí ìkìlọ náà lélẹ̀ nínú àtẹ̀jáde…

Ìṣòro Owó/Èpò: Gómìnà Makinde Dá Àwọn Ọkọ Àkérò Ọ̀fẹ́ Sí Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Gómìnà Seyi Makinde tí ìpínlẹ̀ Ọyọ tí kéde àwọn ọkọ Àkérò Omituntun Mass Transit ọ̀fẹ́ látí mú ìrọ̀rùn bá àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ náà. Èyí ní ó kéde látàrí ìdààmú ònìbejì tí owó náírà àtí àìtó èpò tó tí dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lagada…

Ẹ́ Fí Àyè Gbá Àwọn Aṣojú-Owó Látí Wá Ojútùú Sí Owó Tuntun – Ìgbákejì Ààrẹ Pàrọ̀wá Fún Àwọn…

Ọnà sí ìṣòro tí àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń kojú lórí owó tuntun ní kí Bánkì gbogbogbò orílẹ̀-èdè yìí (Central Bank of Nigeria CBN) àtí àwọn Bánkì Ìṣòwò (Commercial Banks) fí ayé púpọ̀ díẹ̀ síì gbà àwọn aṣojú owó àti FinTech látí kojú…
button