Ọnà sí ìṣòro tí àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń kojú lórí owó tuntun ní kí Bánkì gbogbogbò orílẹ̀-èdè yìí (Central Bank of Nigeria CBN) àtí àwọn Bánkì Ìṣòwò (Commercial Banks) fí ayé púpọ̀ díẹ̀ síì gbà àwọn aṣojú owó àti FinTech látí kojú ìṣòro owó tuntun náà kí ọ bá lé dé gbogbo ìgbèríko lorílẹ̀-èdè yìí.
Ìgbákejì Ààrẹ sọ èyí ní Ọjọ́ Ẹtì ní Abuja nígbàtí ó pé pàdé pẹ̀lú àwọn alẹnu-lọ̀rọ̀ ní ilé-iṣẹ́ FinTech látí ṣàwarí àwọn ọnà ádínkù ìṣòro náà.
Tún kà nípa: Ààrẹ Buhari Gbé Ìgbésẹ̀ Akin Lórí Ọ̀wọ́n-gógó Owó
Ìgbákejì Ààrẹ sọ̀rọ̀ náà tẹ́le tí Ààrẹ tó sọ níbí ìpàdé pẹ̀lú àwọn Gómìnà All Progressives Congress APC ní gbangban ilé iṣẹ́ Ààrẹ bó ṣé fí dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè náà lójú pé ipenija náà yóò di òun ìgbàgbé láìpẹ́.
Ọ̀kan nínú àwọn alẹnu-lọ̀rọ̀ dàba pé kí àwọn bánkì ṣé ádínkù ìdíyelé USSD àtí ìyè òwò data, kí àwọn élétó náà sí yọ́ ìdíyelé tí wọ́n náà kúrò pátápátá ní àkókò ipenija yìí, kó lè bá fí ẹ̀mí àwọn àrà ìlú bálẹ̀.
Lekan Orenuga
Leave a Reply