Àjọ tó ń mójú tó ètò ìsìnlú àwọn ọdọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà National Youth Service Corps (NYSC) ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi tí kílọ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tí 2023 Batch ‘A’ stream ‘1’ láti má ṣé iṣẹ́ tó lè bá ọjọ́ iwájú wọ́n jẹ̀.
Adari NYSC ní Ìpínlẹ̀ náà Ìyàáfín Mercy Bamai fún wọ́n ní ìmọràn yìí làkókò ayẹyẹ ìparí tí 2023 Batch ‘A’ stream ‘1’ ìlànà ìtọ́nisọ́nà, ní Old MacGregor College Afikpo, North Local Government Area tí Ìpínlẹ̀ Ebonyi.
![]()
Tún kà nípa: Olùdarí gbogbogbòò NYSC ṣèkìlọ̀ lórí ìrìnàjò àìtọ̀nà
“Ó rọ̀ wọ́n kí wọ́n yàgò fún Ìrìn-àjò òru, irin-ajo láì dàgbéré, ìkópa nínú òṣèlú ẹlẹyamẹya àtí ẹgbẹ́ òkùnkùn. Ó sí bẹ̀bẹ̀ pé kí wọ́n lò àwọn iṣẹ́ ọwọ́ tí wọ́n kọ́ làkókò ìdánilẹ́kọ̀ wọ́n.
Ó dín díẹ̀ lẹgbẹ̀rún àwọn ọdọ lápápọ̀ ni 2023 Batch “A” stream ‘1’ tí àwọn Ọkùnrin jẹ́ irínwó lé méjìdínlógún 418 tí Obìnrin sí dín díẹ̀ ní ọ̀ọ́dẹ́gbẹ̀ta 473.
Lekan Orenuga
Leave a Reply