Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

Ó GBÓNÁ FẸLI-FẸLI

This is a category for LATEST NEWS

Tunisia sọ àwọn gbajúgbajà akọ̀ròyìn méjì sẹ́wọ̀n ọdún mẹ́ta ààbọ̀

Ilé ejọ́ Tunisia dá ẹjọ́ tí ó sì sọ àwọn gbajúgbajà akọ̀ròyìn méjì sẹ́wọ̀n ọdún mẹ́ta ààbọ̀ lórí ẹ̀sùn yíyọ́ owó orí sílẹ̀, tí ìkan lára ẹbì sọ pé ìgbẹ̀san ìjábọ̀ tí wọn ń ṣe ni. Awọn akọroyin naa, Bohran…

Makinde Ni Okòwò Ti Fẹṣẹ Múlẹ̀ Ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Bí Ladoja, Igbákejì Gómìnà Àti Àwọn Aṣòfin Kan Ṣe…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti sọ di mímọ̀ pé ìṣèjọba òun ti dé ìpele eléyìí to fihàn pé okòwò ti rẹ́sẹ̀ walẹ̀ pẹ̀lú sisan owó tí kò dín ní Bílíọ̀nù Mẹrinlelogun (N24b) gẹ́gẹ́ bíi owó oṣù òṣìṣẹ́ ni Ìpínlẹ̀ àti Ìjọba Ìbílẹ̀. Bákan…

Olubadan ní ìgbàgbọ́ nínú ìgbésẹ̀ tí Ààrẹ Tinubu gbé lórí ọ̀rọ̀ ààbò

Ọba ilú Ìbàdàn, Olúbàdàn ti ilẹ̀ Ìbàdàn, Gúsù Iwọ̀ Òòrùn Nàìjíríà, Ọba Rasidi  Ladoja, ti sọ pé àwọn ìpeniníjà àìláàbò Nàìjíríà kìí ṣe nǹkan tí kò le di àfìsẹ́yìn, tí ó mọ̀ dájú pé Ààrẹ Bola…

Nàìjíríà, Amẹrika túnbọ̀ fìdí àjọṣepọ̀ ààbo wọn múlẹ̀ fún òmìnira ẹ̀sìn

Ìjọba Nàìjíríà ti túnbọ̀ fìdíi ìfọkànsì rẹ̀ ní́ dídáábòbò ẹ̀mí àti fífi ìdí ààbò rinlẹ̀ jákéjádò orilẹ-ede mulẹ,  – lẹ́yìn ìpàdé àpérò Nàìjíríà – Egbẹ Ajọṣepọ Iṣiṣẹ Amẹrika ba agbegbe orílẹ̀-èdè tọrọ naa kan…
button