Browsing Category
ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GÌN ÀTI ÀYÍKÁ
Ìpínlẹ̀ Taraba Jé ilé Agbára Ṣugbọn Ko Sí Àtìlẹ́yìn.
Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Kashim Shettima nínú ọ̀rọ̀ sọ wí pé ìpínlẹ̀ Taraba jẹ ilé agbára fún ohun ògbìn ṣugbọn konsi àtìlẹ́yìn fún.
Igbákejì Ààrẹ Shettima sọ èyí di mímọ lásìkò ajọdun ohun ògbìn ọdún 2025 to waye ni Jalingo.
Ó…
Gbíngbin Ìgi Fún Àjọyọ̀ Ọjọ́ìbí Àti Ọdún Tuntun Mú Ìyí Wa Púpò : Ẹgbẹ́ NCF.
Adari àgbà pátápátá fún ẹgbẹ́ NCF, Joseph Onaja ti pé àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ma gbin igi fún Ayẹyẹ ojo-ibi, òní èyí ṣe pàtàkì jù ṣíṣe owó kumokumo ló.
Ọnaja sọ èyí di mímọ̀ ni ìlú Abuja níbi ayẹyẹ gbìn gbìn Igi to wáyé.
Ó ní…
Ìrọ̀rùn Dé Ní Ìpínlẹ̀ Plateau : Àjọ Kan Tí K ì í Ṣe Ti Ìjọba Pín Ohun Èlò Ọ̀gbìn Fún…
Àjọ (Blessigs Projects), ní Ọjọ́ Ìṣẹ́gun pín àwọn ohun èlò ọ̀gbìn fún àwọn obìnrin márùndínlógóje, ní Irigwe Cheifdom, Ìjọba Ìbílẹ̀ Bassa, Ìpínlẹ̀ Plateau
Ọ̀gbẹ́ni Lawrence Zongo tí ó jẹ́ alákòso àjọ…
Ètò Ìsúná Owó Fún Ètò Ọ̀gbìn Ti Ọdún 2025 Ní Ìpínlẹ̀ Bauchi Kéré Jọjọ- Àwọn Àgbẹ̀…
Ìgbìmọ̀ tí ń wòye sí ètò ìsúná owó ní Ìpínlẹ̀ Bauchi ti korò ojú látàrí bí ètò ìsúná ètò ọ̀gbìn ọdún 2025 se kéré jọjọ
Adarí ìgbìmọ̀ náà Arábìnrin Tabawa Atiku ni ó sọ ọ̀rọ̀ náà nígbà tí…
Àjọ BORBDA Ní Àfojúsùn, Ìgbáradì Fún Ìpèsè Oúnjẹ Lọ́pọ̀ Yanturu
Ọ̀gá Àgbà Àjọ BORBDA, Ọ̀mọ̀wé Fẹmi Adekanbi ti fi ọ̀rọ̀ léde pé àjọ náà yóò gbìyànjú láti mú àdíkù bá owó oúnjẹ rírà, tí oúnjẹ yóò sì sùwábọ̀ lọ́pọ̀ yanturu
Adekanbi síṣọ lójú ọ̀rọ̀ náà ní ìlú…
Àjọ Kan Kọ́ Àwọn Obìnrin Ní Ẹ̀kọ́ Iṣẹ́ Oko Ìgbàlódé Àti Nípa Ìmọ̀ Ojú Ọjọ́
Àjọ International Centre for Environmental Health and Development (ICEHD) ti kọ́ Ọgọ́rùn ún àwọn àgbẹ obìnrin ní ìlú Abuja àti agbègbè rẹ̀ ni ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀ ojú ọjọ́ àti iṣé oko nípa ti ìgbàlódé.
Nígbà ti ó n sọ̀rọ̀ níbi…
Àjọ Afdb Gbin Ọrọ Ajé Mílíọ̀nù Mejọ Nípa Ti Omi Káàkiri Ilẹ̀ Adúláwọ̀
Àjọ African Development Bank Afdb ti gbin ọrọ Ajé Mílíọ̀nù Méjọ nípa ti ohun èèlò Omi káàkiri ogójì Ilẹ̀ Adúláwọ̀ láti ọdún 2020, ti yóò wúlò fún àwon èniyàn tó jù méjìléàádọ̀rún mílíọ̀nù.
Adarí àjọ Water Development and Sanitation…
Wọ́n Sọ Ọmọ Orílẹ̀-èdè China Méjì Sẹ́wọ̀n Látàrí Ìwakùsà Ní Ọ̀nà Àìtọ́ Ní Ìpínlẹ̀ Kwara
Adájọ Ilé ẹjọ́ tó ga julọ ni orílẹ̀-èdè tó kalẹ si ìlú Ìlọrin, Abimbola Awogboro ti sọ ọmọ
Orílẹ̀-èdè China Méji Yang Chao ati Wu Shan Chuan si ẹ̀wọ̀n fún ẹsun Iwakusa ohun alumọni ní ọnà aitọ́ ní ìpínlẹ̀ Kwara.
Wọn dáwọn lẹjọ pẹlu…
Ìgbìmọ̀ Ni Ìpínlẹ̀ Jigawa Ṣe Àtúnṣe Ibí Ìtajà Ẹran Láti Mu Ìdàgbàsókè Wá.
Ìjọba ìbílẹ̀ Giri ni ìpínlẹ̀ Jigawa ti ṣe àtúnṣe fifẹ ibí ìtajà ẹran láti túbọ̀ mú ètò ìtajà dàgbà sókè ni ipinle náà.
Ìròyìn yìí di mímọ̀ láti ẹnu Fahad Muhammad tó jẹ agbẹnusọ fún ìgbìmọ̀ ìpínlẹ̀ Jigawa.
Muhammad sọ wí pé àtúnṣe…