Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GÌN ÀTI ÀYÍKÁ

Ìmọ́tótó Ni Ó L e è Ṣẹ́gun Àrùn Gbogbo: Akọ́ṣémọṣẹ́ Pè Fún Ìmótótó Láti Kojú…

Akọ́sẹ́mọṣẹ́ Nípa Ètò Ìlera, Arábìnrin Veronica Augustine ti pàrọwà sí gbogbo ọmọ Nàìjíríà láti mú ìmọ́tótó ní ọ̀kúkúdùn lójúnà àti kojú ìsòro gbogbo àrùn   Ó sọ ọ̀rọ̀ náà ní ìlú Abuja, ní ọjọ́…

Ilé -Iṣẹ́ Tí Ó Wà Ní Títìpa Látàrí Bíba Afẹ́fẹ́ Jẹ́ Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Ti Bẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́…

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti sí ilé isẹ́ tí ó ń lo táyà gẹ́gẹ́ bí ohun èlò ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, èyí tí ó ti wà ní títìpa tẹ́lẹ̀rí látàrí bíba afẹ́fẹ́ jẹ́ àti kíkó ìnira bá àwùjọ   Kọmísọ́nà fún…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Se Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Lórí Ìmọ́tótó Oúnjẹ Fún Àwọn Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta…

Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ti pinnu láti tẹ̀síwájú lórí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn olùtajà lórí ìmọ́tótó, ìpamọ́ ati síṣe akẹ́tọ̀ọ́ àwọn ohun jíjẹ lójúnà àti mú kí oúnjẹ pọ̀ yanturu   Arábìnrin Abisọla Olusanya tí…

Àsọyépọ̀ Wáyé Láàrin Àwọn Ìpínlẹ̀ Ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Láti Mú Àlékún Bá…

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò pẹ̀lú ìpínlẹ̀ Niger àti Kwara láti mú ìgbòòrò bá ìpèsè oúnjẹ láàrin àwọn ìpínlẹ̀ náà nínú àgbékalẹ̀ kan tí ó wáyé ní ìpínlẹ̀ Èkó   Ìgbésẹ̀ náà wáyé…

Ìjọba Àpapọ̀ Àti Ìpínlẹ Kebbi Ti Parí Ètò Láti Mú Ìgbòòrò Bá Ètò Ọ̀gbìn Èyí Tí…

Ìjọba àpapọ̀ àti Ìpínlẹ̀ Kebbi ti gbé ìgbésẹ̀ akin láti mú ìgbòòrò bá ètò ọ̀gbìn èyí tí yóò mú àdíkù bà ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ, tí oúnjẹ yóò sì wà lọ́pọ̀ yanturu   Mínísítà Fún Ètò Ọ̀gbìn àti…

Ìsẹ̀lẹ̀ Idagiri Ẹgbẹ̀rún Kan-lé-lẹ́ẹ̀dẹ́ẹ́gbẹ̀ta Ní Ó Wáyé Ní Ìpínlẹ̀ Eko Nínú Ọdún…

Àjọ tí ó ń mójútó ìsẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì ní ìpínlẹ̀ Eko, (LASEMA) ti sọ pé, ó tó ìsẹ̀lẹ̀ ẹgbẹ̀rún kan lé lẹ́ẹ̀dẹ́ẹ́gbẹ̀ta tí ó wáyé láàrin ọjọ́ kíní osù kíní ọdún 2023 sí ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n osù kejìlá…
button