Browsing Category
ÌRÒYÌN ÀṢÀ ÀTI ÌṢE YORÙBÁ
This is a category for culture and life news
Gowon Tún Ṣèlérí Látí Tọjú Ìtàn Àjogúnbá Nàìjíríà
Ọkàn nínú àwọn àgbà Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Olórí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kán rí, General Yakubu Gowon, tí tún ṣé ìdánilójú rẹ̀ láti ṣé ìtọjú àwọn ìtàn àjogúnbá Nàìjíríà.
Gen. Yakubu Gowon sọ èyí nígbàtí Ẹgbẹ́ Akọtan tí…
Aláàfin Ìlú Ọ̀yọ́ Ṣe Ìpàdé Pẹ̀lú Àwọn Oṣiṣẹ Ààfin, Pé Fún Ìsọ̀kan Láàrin Wọn
Aláàfin ìlú Ọ̀yọ́, Ọba Abímbólá Akeem Owoade I ti jẹ kó di mímọ̀ pé ìbáṣepọ̀ láàrin àwọn òṣìṣẹ́ kò ṣeé fi ọwọ́ rọ́ sẹ́yìn.
Ọba Owoade tẹnu mọ́ pé ìbáṣepọ̀ tó dan mọ́ọ́rán ṣe pàtàkì fún isé àti iṣẹ́ ojoojúmọ́, tó sì tún jẹ́ ọ̀pákútẹ̀lẹ̀…
Aṣòfin Oluremi Tinubu Pé Fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Olori Ìlú Láti Fòpin Sí Dídá Abẹ Fún Ọmọbìnrin (FGM)
Àyà Ààrẹ Orilẹ Èdè Nàìjíríà, Aṣòfin Oluremi Tinubu ti ké sí àwọn Olórí ìlú àti agbègbè láti sa ipá wọn lójúnà àti fi òpin sí dídá abẹ fún ọmọ obìnrin (FGM), kòkòrò HIV/AIDS àti àrùn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀.
Oluremi Tinubu lo fi ọ̀rọ̀ lédè lásìkò tó…
Gómìnà Adamawa Ṣé Ìlérí Àtìlẹ́yìn Fún Àwọn Ilé-iṣẹ́ Ìbílẹ̀
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Adamawa, Ahmadu Fintiri, tí tún fí ìdí rẹ̀ múlẹ̀ sí látí ṣé àtìlẹ́yìn fún àwọn ilé-iṣẹ́ ìbílẹ̀ fún pàtàkì ìdàgbàsókè ìpínlẹ̀ náà àti Orílẹ̀-èdè lápapò.
Gómìnà sọ èyí dí mímọ̀ l'àkókò ayẹyẹ Ọjọ́ Ọdún àpapọ̀ Nnoma-Jhar…
Mínísítà Àṣà Kí Àlàáfín Tuntun Ti Ìlú Ọ̀yọ́ Kú Oríire
Mínísita orílè-èdè yìí fún àṣà, iṣẹ, Ìrìn-àjò òun igbafe àti ọgbọ́n àtinúdá ọrọ̀ ajé, Hannatu Musawa ti kí Àlàáfín tuntun ti Ìlú Ọ̀yọ́, Ọba Abimbola Akeem Owoade, kú oríire, ti ìgorí ìtẹ́ baba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Aláàfin…
Ìṣèjọba Mi Koni Tojú Bọ Ìlànà Yíyan Ọmọ Oyè – Makinde
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde tí jẹ ko fi mímọ̀ pé ìṣèjọba òun yóò tẹ síwájú láti máa tẹlé ìlànà tó tọ nínú ìṣàkóso Ìpínlẹ̀ náà
Bákan náà ló ṣàlàyé pé ìṣèjọba òun kò ní tojú bọ ọba jíjẹ àti ìlànà yíyan ọmọ oyè ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.…
Oníṣẹ́ Ọnà Ké Gbàjarì Pé Isẹ́ Ọnà Àti Àṣà Wa Kò Gbọdọ̀ Parun
Oníṣẹ́ ọnà kan ní orílẹ̀-èdè yìí, Isah Lawan, ti ke gbajari sì àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè yìí pé isé ọnà àti àṣà wa ti fẹ máa lọ sì oko ìparun.
Ọgbẹni Lawani ti o ti wá nidi isẹ́ ọnà láti bi ogójì ọdún sẹyìn, ẹni ti o n sisẹ́ ní Eko Hotel and…
Àjọ Adarí Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Fẹ́ Dá Ọọ̀ni Ti Ilé Ifẹ̀ Lọ́lá
Ẹlẹ́kẹrìnlá irú rẹ àjọ ipade ẹyẹ Adari ilé Adúláwọ̀ tí wọ́n gbékalẹ̀ lábẹ́ àjọ UN International Peace Governance Council (UNIPGC), ẹ̀ka ilẹ̀ Adúláwọ̀ yóò fi àmì ẹyẹ ọlọlá- Grand Commander of Peace fún Ọba Adeyeye Babatunde Enitan…
Aṣáájú Nàìjíríà Gbá Àkọlé Àṣà Ìbílẹ̀ Tó Gíga Jùlọ Ní Akwa Ibom
Ìgbìmọ̀ Àwọn Alàkóso ìbílẹ̀ tí Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom tí ṣé ọla fún Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu pẹ̀lú àkọlé tó gá jùlọ tí "Otuekong," èyí tó ṣàfihàn Ààrẹ gẹ́gẹ́bí Alàkóso àgbà ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom.
Ibù-ọlá fún Ààrẹ náà ló wáyé ní ọjọ́ Ẹtì ní…