Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ

This is a category for business news

Dangote lu Ìjọba Àpapọ̀ Lọ́gọ Ẹnu Fún Àtìlẹyìn Lórí Àseyọrí Ilé Isẹ́ Ìfọpo

Ààrẹ Ilé iṣẹ́ Dangote, Aliko Dangote ti fi ìdùnnú rẹ̀ hàn, Ó sì dúpẹ́ lọ́wọ́ ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu fún àtìlẹyìn, ìmọ̀ràn àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ fún ìkẹṣejárí ilé iṣẹ́ ìfọpo èyí tí ó dá sílẹ̀ ní ìlú Èkó…

Ìgbésẹ̀ Ìjọba Àpapọ̀ Láti San Ìdajì Nínú Owó Orí Ọkọ̀ Lásìkò Ọdún Tuntun Kò So Èso…

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìjọba àpapọ̀ san ìdajì nínu owó ọkọ̀ lásìkò ọdún tuntun, àwọn awọkọ̀ fi ẹ̀dùn ọkaǹ hàn pé níse ní owó ọkọ̀ tún gbówó lórí ju bí ó ti se yẹ lọ À̀àrẹ Tinubu kéde ìrànwọ́ lórí…

Àrọwà Ti Wá Fún Ọmọ Nàìjíríà Láti Siṣẹ́ Takun-takun Fún Ìsàgbékalẹ̀ Ètò Ọrọ̀ Ajé…

Alága Àti Olùdásílẹ̀ Ilé Iṣẹ́ Funab, Alhaji Ibrahim Mohammed Ajia ti késí gbogbo ọmọ Nàìjíríà láti fi ọwọ́ sowọ́pọ̀ fún ìsàgbékalẹ̀ ètò ọrọ̀ ajé tí ó yè kooro èyí tí yóò mú ìdàgbàsókè bá Orílẹ̀-èdè…
button