Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
UNICEF, Standard Charted Yóò Wá’ṣẹ Fún Àwon Ọmọ Obìnrin Ẹgbẹ̀rún Kan Àbọ̀
Standard Chartered Foundation àti Àjọ UNICEF’s Generation Unlimited (UNICEF GenU) ti kéde àjọṣepọ̀ láti ran àwọn obìnrin ẹgbẹ̀rún-kan-àbọ̀ ọ̀dọ́ lọ́wọ́ láti rí iṣẹ́ tó dára ní Kenya àti Nàìjíríà.
Ajọṣepọ ọdún mẹ́ta náà yóò dojúkọ àwọn…
Minisita Bẹ̀rẹ̀ Ìlànà Ìmúṣẹ fún Àdéhùn Àlàáfíà Àwùjọ Nàìjíríà àti Türkiye
Minisita fún Ọ̀rọ̀ Àwọn Obìnrin àti Ìdàgbàsókè Àwùjọ Nàìjíríà, Imaan Sulaiman-Ibrahim, ti ṣe ìpàdé gíga pẹ̀lú Minisita fún Ìdílé àti Àwọn Iṣẹ́ Àwùjọ ti Türkiye, Mahinur Özdemir Göktaş láti bẹ̀rẹ̀ ìmúṣẹ àwọn àdéhùn lórí ìṣọ̀kan Ìdílé àti…
Ìlú Ìbàdàn Yóò Fọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹlú Ilé Ẹ̀kọ́ Ìwádìí Ògbìn Kòkó Ni Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà (CRIN) Fún…
Nínú ìpinnu rẹ̀ láti mú ìdàgbàsókè dé bá ọrọ̀ ajé àti ìgbéga okòwò, Olúbàdàn ilẹ Ìbàdàn, Ọba Rashidi Adewolu Ladoja, Arusa I ti ké sí ilé ẹ̀kọ́ ìwádìí ọ̀gbìn Kòkó ni Orilẹ èdè Nàìjíríà (Cocoa Research Institute of Nigeria, CRIN) láti jíròrò…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Pẹ̀lú Orílẹ̀ Èdè Netherlands Fọwọ́sowọ́pọ̀ Lórí Ọ̀gbìn Tòmátò Pẹ̀lú Ìmọ̀ Ẹ̀rọ…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti gúnlè ṣíṣe àmúlò anfààní ìmọ̀ ẹ̀rọ aláìlééfín láti ṣe ogbin Tòmátò lọ́pọ̀ yanturu pẹ̀lú Orílẹ̀ Èdè Netherlands.
Ẹni tíì ṣe Alákòóso àgbà ilé Àjọ Ìdàgbàsókè Òkòwò Iṣẹ́ Àgbẹ̀ ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ (Oyo State Agribusiness…
Ilé-iṣẹ́ ‘Galaxy Backbone’ Tí Ṣetán Lati Ṣayẹyẹ Ogún Ọdún
'Galaxy Backbone Limited' (GBB), ilé-iṣẹ́ Ayélujára tó ga jùlọ ní Nàìjíríà àti olùpèsè iṣẹ ayélujára tí Ìjọba Àpapọ̀ tí kéde ayẹyẹ ogún ọdún ilé-iṣẹ́ náà tí yóò wáyé ní Oṣu Kẹfa ọdún 2026.
Èyí ni a sọ ninu atẹjade kan ti Olori Ìròyìn…
Òṣùwọ̀n Ìtajà Tí Nàìjíríà Ti Dínkù Sí Ìdá 15.15 Nínú Ọgọrùn – NBS
Ẹgbẹ́ Àjọ Àgbékalẹ̀ Ìṣirò ti Orílẹ̀-èdè (NBS) sọ pé ìwọ̀n ìtajà tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dúró sí ìdá mẹ́ẹ̀dógún àti díẹ̀ nínú ìdá ọgọ́rùn (15.15%) ní oṣù Kejìlá ọdún 2025, èyí tí ó fi hàn pé ìwọ̀nba ìdínkù owó náà jẹ́ èyí tó pọ̀jù owó oúnjẹ.…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano Ṣe Iranlọwọ Owò Fún Àwọn Obínrin Láti Bẹ́rẹ Okòwò
Gómìnà ìpínlẹ̀ kano, Kabir Yusuf ti fún àwọn Obìnrin ìpínlẹ̀ náà ni ẹgbẹrun Náírà láti fi bere òkòwò.
Ó ní èyí yóó mu ki òsì ati ìyà dì kun ni ìpínlẹ̀ náà láàrin àwọn Obìnrin
Nínú àtẹ̀jáde láti ọwọ̀ agbẹnusọ fún Gómìnà Sanusi Bature ni…
Orílẹ̀-èdè Algeria Yóò Rí Bílíọ̀nù Mẹ́ta Dọ́là Owó Ẹ̀yá Gbà Láti Ọ̀dọ̀ Báǹkì Ìdàgbàsókè Ìsìláàmù
Ààrẹ Banki Idagbasoke Isilaamu - "Islamic Development Bank" Muhammad Sulaiman Al Jass ti sọ pé Orílè-èdè Algeria yoo ri Biliọnu Mẹta Owó dọ́là ya laarin odun mẹta tẹ̀léra lati fi ṣe àwọn àkànṣe iṣẹ ìdàgbàsókè.
Ààrẹ ilè…
Ilé Ifowopamọ ECOWAS Ti Ṣetán Láti Sí Ilè Ifowopamọ Si Orílè-èdè Cote d’voire.
Ilé Ifowopamọ ECOWAS fún ìdọ́kọ̀wọ̀ àti ìdàgbàsókè ti buwolu ìwé ajọṣepọ láti da ilé iṣé silẹ ni Orílẹ̀-èdè Cote d'Ivoire.
Ni ìlú Abidjah ni ọrọ àjọsọpọ tó dan mọ́rán yii wáyé láàárín ìjọba Orílẹ-èdè Cote d'Ivoire èyí tí Mínísítà fún òrò…
Owó Orí Ọjà Amẹ́ríkà Dẹ́rùba Ọrọ̀ Ajé Ilẹ̀ Adúláwọ̀ -Akọ́sẹ́mọsẹ́ Ọmọ Orílẹ̀-èdè Màláwì
Owó orí ọjà Amẹ́ríkà lórí ọrọ̀ ajé ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ sàkóbá bá ọrọ̀ ajé wọn, orílẹ̀-èdè Màláwì jẹ́ ọ̀kan, akọ́sẹ́mọ́sẹ́ nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú-Maclan Kanyang’wa sọ èyí.
Ó sọ pé, oye owó tí wọ́n ń ta nǹkan ní…