Gómìnà Ipinle Sokoto Yàn Olùdámọ̀ràn Pàtàkì Mọkanla
Gomina Ìpínlẹ̀ Sókótó Aminu Tambuwal, ti bọwọ́ lu yíyàn Olùdámọ̀ràn pàtàkì mọ́kànlá.
Nínú ọ̀rọ̀ sísọ láti ẹnu akòwé àgbà fún Ìpínlè Sokoto, Ọ̀gbéni Mainasara Ahmad
lo ti jáde.
Àwọn Olùdámọ̀ràn pàtàkì tuntun tí ó sọ jáde…