Take a fresh look at your lifestyle.

Akẹ́kọ̀ọ́ Tó Ṣẹ̀ṣẹ̀ Yege Jáde Ní UNILAG, Precious Okoye Gba Àmì Ẹ̀yẹ “Miss Africa Calabar…

Akẹ́kọ̀ọ́ Tó Ṣẹ̀ṣẹ̀ Yege Jáde Ní U Ọmọ ọdún mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ti ìmọ̀ ẹ̀rọ Botany ní Ifáfitì Èkó, University of Lagos (UNILAG), ti gba àmì ẹ̀yẹ ẹlẹ́ẹ̀kẹfà irú rei ti Miss Africa Calabar ti ọdún yìí. Adúmáadán arẹwà obìnrin náà kó leè…

Ìpínlẹ̀ Kano: Àjọ Agro Project Fún Akẹ́ẹ̀kọ́ Márùndínlọ́gọ́fà Ní Síkọ́láshìpù

Àjọ Kano state Agro Pastoral Project, KSADP, ti fún olùgbé ìpínlẹ̀ kano ní Síkọ́láshìpù tí iye rẹ̀ tó Mílíọ̀nù lọnà ọgọ́fà ó lé mẹ́jọ, àti ẹgbẹ̀rún lọ́nà igba o lé àádọta Náírà, gẹ́gẹ́ bí Alàkóso àjọ, ọ̀gbéni Ibrahim Garba ní…
button