Take a fresh look at your lifestyle.

Orílè-èdè Nàìjíríà Darapọ̀ Mọ́ Báǹkì Ilẹ̀ Gẹẹsi Fún Àtúnṣe Àti Ìtèsíwájú

Wọ́n ti gba orilẹ̀-ède Nàìjíríà wọlé bí ọmọ ẹgbẹ́ bánkì àjọ European Bank for Reconstruction and Development (EBRD). Mínísítà ètò owó àti Olùdarí ètò ọrọ̀ ajé, ọ̀gbẹ́ni Wale Ẹdun, ló sọ eléyìí di mímọ̀ níbi Ìpàdé àjọ EBRD ọdún 2025…

Ètò Ìlera Ọ̀fẹ́: Makinde Ṣíde Ìfilọ́lẹ̀ Ìlera Ọ̀fẹ́ Ní Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá/Ìlà-Oòrùn Ìbàdàn.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti jẹ ko di mímọ̀ pé ìṣèjọba òun yóò tẹ síwájú láti máa pèsè ètò ìlera lójúnà àti ri dájú pé ará ìlú wa ni ìlera pípé eléyìí tí yóò mú kí ọrọ̀ ajé rú gọ́gọ́ síi, ti ìṣẹ yóò sì dínkù ni àwùjọ. Makibde…

Àwọn Adarí Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ṣetán Ìpàdé Ìgbàlà Ọmọ Ẹgbẹ́ Kúrò Lọ́wọ́ Ìsákiri Lọ Inú Ẹgbẹ́ Òṣèlú Míràn

Gómìnà àti gómìnà tẹ́lẹ̀rí lábẹ́ òṣèlú ẹgbẹ́ People’s Democratic Party (PDP) péjọpọ̀ si ìlú Abuja láti wà ọ̀nà àbáyọ sì ìsákiri àwọn ọmọ ẹgbẹ lọ sin ẹgbẹ́ òṣèlú mìíràn. Àwọn to peju pèsè síbi ìpàde náà láti ri,…
button