Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Ìlà Oòrùn Gúsù Ti Kìlọ Látàrí Ìpè Ìpàdé Àwọn Alẹ́nulọ́rọ̀ Tó Jẹ́ Òfegè

Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Ìlà Oòrùn Gúsù ti kìlọ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀ láti má ka ìpè ipàdé pàjáwìrì àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ ní Abuja sí. Nínú àkọsílẹ̀ ìròyìn kan, alukoro ẹgbẹ́ ní ẹ̀ka ìlà oòrùn gusu, Chigozie Igwe, tẹnumọ…

Ètò Ìkànìyàn Ṣe Pàtàkì Fún Ìgbáradì Ọjọ́ Iwájú Nàìjíríà – Ààrẹ Sẹ́nètì

Ààrẹ àwọn Senetọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sẹ́nétọ̀ Godswill Akpabio ti sọ pé ó pan dandan láti ṣe ètò Ìkànìyàn láti lè jẹ́kí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pèsè fún ọjọ́ ọlá èniyàn rẹ. Sẹ́nétọ̀ Akpabio sọ pé ó ye kí ètò ìkànìyàn náà ti wáyé…

Ọdún Egúngún Lágbayé Ti 2025: Makinde Pinnu Ìgbélárugẹ Àṣà Fún Àgbéga Ọrọ̀ Ajé

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti tẹnu mọ́ pé ìṣèjọba òun yóò máa ṣe atilẹyin fún ìmúgbòòrò àṣà àti ìgbélárugẹ ìṣẹ̀dálẹ̀ ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Gómìnà ló síṣọ lójú ọ̀rọ̀ yìí níbi àṣèkágbá ọdún Egúngún Lágbayé ti ọdún 2025, ayẹyẹ…
button