Take a fresh look at your lifestyle.

Báńkì fún Iṣẹ́ Àgbẹ̀ Gbóríyìn fún Ìgbìyànjú Ìyàwó Àkọ́kọ́ Lórí Oúnjẹ Tí Kò Péye

Olùdarí Àgbà fún Báńkì fún Iṣẹ́ Àgbẹ̀, Ayo Sotinrin ti gbóríyìn fún àwọn ètò iṣẹ́ àgbẹ̀ àti oúnjẹ tí Ìyàwó Àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà, Sẹ́nétọ̀ Oluremi Tinubu, ṣe, ó sì ṣàpèjúwe wọn gẹ́gẹ́ bí àwọn ìgbòkègbodò tó lágbára tó ń mú ààbò oúnjẹ lágbára…

Makinde Ṣí Gáráàjì Ọkọ̀ Àti Àwọn Ibùsọ̀ Ìtajà 540 Ni Ọjà Bódìjà, O Pàṣẹ Ki Àwọn Ọlọ́jà Kúrò Lójúu…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣí Gáráàjì àti Ibùsọ̀ ìtajà ìgbàlódé 540, eléyìí tí Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá-Ìbàdàn kọ́ sí ọjà Bódìjà, to sì pàṣẹ ki àwọn òntàjà to wà lójúu pópó láti gba àwọn Ibùsọ̀ náà láì san owó. Gómìnà, ẹni…

Ilé Asòfin Èkó Fọwọ́ Sí Àdéhùn Àwon Ilé-isé Méjì Tí Yóò Máa Bá Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Sisẹ́

Ilé Ìgbìmò Asòfin Ìpínlè Èkó ti fowó sí àdéhùn àwon Ilé-isé méjì tí yóò máa bá ìjoba Ìpínlè Èkó sisé láti túbò mú ìgbèrú bá èka ìmójútú ìdòtí àti èka ìrìnnà okò ilè. Àwon Omo egbé Ile Asòfin náà fowó sí àdéhùn náà lójó Ajé…
button