Camilla Di Olórí Tuntun Ni Ààfin Ọba Charles III
Camilla ní ìyàwó, olufọkantan àti ìfẹ́ ayé Ọba Charles fún ọdún mẹ́tàdínlógún. Ní báyìí, O tí di Olórí Ọba.
Ọpọ ènìyàn ló tí mọ lára láti máa rí Camilla ní ẹgbẹ ọkọ rẹ̀ níbí ayẹyẹ àti ajọyọ orílẹ-èdè, ṣùgbọ́n o ní àwọn tí bẹrẹ, ọjọ́…