Take a fresh look at your lifestyle.

Àárẹ̀ Nàìjíríà Ṣe ìlérí Láti Tẹ Síwájú Nínú ìfọ̀rọ̀wérọ̀ Lórí Àwọn Ìbéèrè Àjọ Olukọni Ìlé-ẹkó Gíga

Ààrẹ Muhammadu Buhari tí ṣé ìlérí láti ṣé ìtẹ̀síwájú lórí ìfọrọwanilẹnuwo pẹ̀lú àwọn tó níí ṣé ní étò ẹ̀kọ́, làti wà òpin sí rògbòdìyàn ẹgbẹ àwọn olukọni ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Academic Staff Union of Universities (ASUU). O ṣé ìlérí náà ní…

Ìjọba Nàìjíríà Sanwó Ìtanràn Fún Àwọn ènìyàn Mẹ́rìnléláàdọ́rin Tí Àwọn Ọlọ́pàá Fí Ìyà Àìtọ́…

Ìjọba Nàìjíríà tí sàn owo tó jù igba o le mejidinlọgọrin miliọnu naira (289m) fun àwọn mẹrinlelaadọrin (74) lórí bí wọn se tẹ ẹtọ  ọmọniyan  loju mọlẹ ati ẹsun iwa ọdaju tí  awọn ọlọ́pàá kàn hu si wọn . Ìgbìmọ̀ Ìwádìí olómìnira lórí…

EU Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Ètò Láti Ṣé àtìlẹ́yìn fún Ìjọba Awaarawa Ní Nàìjíríà

Àjọ Euroopu (EU) tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ ètò kàn látí jẹ́ kí àwọn ará ìlú ní ìgbàgbọ́ àti igbẹkẹle nínú ètò ìdìbòyàn ati Ìjọba Awaarawa ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Gẹgẹ bí àjọ náà ṣé sọ, wọ́n yóò ṣé ìfilọ́lẹ̀ ètò náà ní Ọjọ́ Ajé, Ọjọ Kejìlá, Oṣù…
button