Take a fresh look at your lifestyle.

Àpèjọ Àgbáyé: Ààrẹ Bùhárí Tẹnumọ́ Pàtàkì Ẹ̀kọ́

Ààrẹ̀ Mùhámmádù Bùhárí ti kéde pé, òbí kankan kò yẹ kí ó fi ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́ ṣe àwàdà,  nítorí pé tí  àwọn ọmọ wọn tàbí àwọn ọmọ tí wọ́n gbà tọ́ bá pàdánù láti kọ́ ẹ̀kọ́, wọ́n pàdánù púpọ̀. Nigbati o…

COVID-19: Àwọn ènìyàn mèjì-le-ni-ojì din ni ẹgbẹ́ta míràn ló tún ti ní ààrùn covid…

Ééjì-lé-ní-òjì dín ní ẹgbẹ̀ta ènìyàn míràn ni ààrùn covid tún ti jẹyọ lára wọn,ní báyìí, àwọn tó ti  ní ààrùn ọ̀hún jẹ́ ọgọ́rún kan àti ààdọ́rin ó lé mẹ́jọ, ẹgbẹ̀rin àti mọ́kànlélógún. Ile-iṣẹ to…

ICPC- àwọn oníṣẹ́ ọlọgbọ́n gbọ́dọ̀ kópa nínú ìwà ìṣẹ̀tọ́ lórílẹ́-èdè

Ìwà-ìṣẹ̀tọ́ ní Orílẹ̀-èdè àti ìlànà ìdúróṣinṣin  Àwọn àjo oníṣówò àti ẹgbẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ nkàn  pàtàkì  sí Ìṣòwò Ìlú. Alaga fun igbimọ to n risi  iwa ibajẹ ati awọn ẹsẹ ti o…

Igbákejì ààrẹ Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀sínbàjò darí àpèjọ àwọn ìgbìmọ̀ àjọ tó ń rísí ìṣòwò

Igbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè, ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀sínbàjò ń darí ìpàdé pẹ̀lú ìgbìmọ̀ àjọ tó ń rísí ìṣòwò lórí ayélujára,ìpàdé náà bẹ̀rẹ̀ ní agogo mọ́kànlá àárọ̀, ní ọjọ́ ọjọ́bọ̀. Gbogbo gomina…

EFCC Gba Mílíónù méérìǹlá-dín-ní-ọ̀tà dín ní ẹgbẹ́rin Fún Àwọn irinṣẹ́…

Ìgbìmọ̀ Aláse  ti fọwọ́sí iye owó tó tó mílíọ́nù mẹ́ẹ́rìǹlá-dín-ní-ọ̀tà dín ní ẹgbẹ̀rin, láti kọ́ ilé àṣẹ àti ìṣàkóso  àti ríra àwọn ohun èlò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ fún ilé iṣẹ́ alátakò náà ní…

Ìjọba Nàìjíríà ṣèlérí láti parí gbogbo àwọn iṣé àṣepatì ní ilẹ̀-ògóni

Ìjọba Nàìjíríà ṣì dúró lórí  àdéhùn rẹ̀ nípa píparí iṣẹ́ àkànṣe ní ilẹ̀ Ògóni fún ìdàgbàsókè ètò-ọrọ̀ ajé ní agbègbè náà. Ijọba Naijiria pe akiyesi pe, iṣẹ akanṣe aṣekagba ilẹ ogoni ti ikọ Niger Delta…

Ààbò Orílẹ̀-èdè: Àwọn ọmọ ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin pè fún àfikún owó láti pèsè ààbò…

Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin Orílẹ̀-èdè ń bèèrè fún  owó  tó jọjú  díẹ̀ síi, fún Àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà àti àwọn ilé-iṣẹ́ ààbò míràn, láti le kojú ewu  rògbòdìyàn tí ó ń da orílẹ̀-èdè náà láàmú.…
button