Ọmọ-ogun Nàìjíríà sọ pé, kò sí ààye fún èyíkéyìí ìwà ìbàjẹ́ àti gẹ́gẹ́ bí ilé-iṣẹ́ tí ó ní ṣe pẹ̀lú àwọn ènìyàn,òhun yóò ríi dájú pé òdodo borí.
Alaye yi waye ni ifesi si atẹjade awọn oniroyin kan, ti o fẹsun kan jagunjagun kan, ti o fi owu pa ololufẹ rẹ ti o n jẹ Jennifer Ugadu,ọmọ ile-ẹkọ giga fafiti ti Niger Delta,Ammasoma.
Gẹgẹbi alaye kan lati olu Ile-iṣẹ Ologun, wọn fi ẹsun kan pe o yin ọmọ ile-iwe naa nibọn ni iyẹwu rẹ,ti o si na papa bora.
Nitorinaa,awọn ọmọ ogun wa n mu da gbogbo eniyan loju pe , ohun yoo mu abajade iwadi naa wasi gbangba to baya.
Leave a Reply