Ìjọba Nàìjíríà ṣe ìlérí pé òhun yóò jẹ́ kí abẹ́rẹ́ àjẹsára covid wà lárọ̀wọ́tó
Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ṣe ìlérí láti ríi dájú pé abẹ́rẹ́ àjẹsára covid wà lọ́pọ̀ yanturu jákèjádò orílẹ̀-èdè náà.
Akọwe ijọba apapọ ati alaga,igbimọ alakoso aarẹ lori aarun covid,Boss Mustapha,fidi…