Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19:Ènìyàn mọ́kàn-léní –òjì-lé-lẹ́ẹ̀dẹ́gbẹ̀ta míràn tún ti ní ààrùn covid

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

53

Àwọn ènìyàn mọ́kàn-lélójì-lé-lẹ́ẹ̀dẹ́gbẹ̀ta míràn tún ti ní ààrùn covid ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ile-iṣẹ to n mojuto ajakalẹ aarun,NCDC ni o fidiẹ mulẹ ni, alẹ ọjọ aiku lori ayelujara wẹẹbu wọn.

Awọn eniyan mọkan-leni-oji-le-lẹẹdẹgbẹta yii jẹyọ ni awọn ipinlẹ mẹtala – Lagos (mọkan-le-loji-le-nigba),Akwa Ibom (mẹrin-le-laadọrun),Enugu (meji-din-laadọta),Oyo (meji-din-laadọta),Anambra (mẹrin-le-lọgbọn), Rivers (mọkandin-logun),Ogun (mẹta-din-logun),Ekiti (mẹẹdogun) ,FCT (mẹsan), Kwara (meje), Abia (marun),Delta (meji), Niger(ẹyọkan).

Lọwọlọwọ bayii,eniyan ẹgbẹ́ẹ́ẹdógún –le- ni- ọ̀kẹ́ mẹ̀sán- o –din- ni- ẹ̀ta- din- lọọgọ́rùn lo ti ni aarun ọhun, ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin- le- ni- ọ̀kẹ́ mẹ̀jọ- o- le- ni- ẹ̀jọ- din- loọgọ́je eniyan si ti gba iwosan, ti ọ̀kan- din- ni- okòó-le-ni-ẹgbẹ́ọ̀kànlá eniyan si ti olóògbé.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.