Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì ààrẹ Ọ̀ṣínbàjò ń darí àpèjọ lórí ayélujára

Ìpàdé ọlọ́sẹ̀ẹ̀sẹ̀  Ìgbìmọ̀ Aláse àpapọ̀ bẹ̀rẹ̀ ní òwúrọ̀ Ọjọ́bọ̀ pẹ̀lú Igbákejì ààrẹ Yẹmí Ọ̀ṣínbàjò. Ọjọgbọn Ọṣinbajo  lo n ṣe alaga ipade naa nitori   Aarẹ Muhammadu Buhari to wa ni ilu Paris, Faranse, fun abẹwo…

Nàìjíríà bá orílẹ̀-èdè Niger Republic kẹ́dùn Lórí Ìpàdánù Àwọn Ọmọdé

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti fi ẹ̀dùn rẹ̀ ránṣẹ́ sí Ààrẹ orílẹ̀-èdè Niger Republic Mohammed Bazoum lórí ikú àwọn ọmọ ilé ìwé mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n, tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ọmọ ọdún márùn-ún àti mẹ́fà, lákòókò tí yàrá ìkàwé wọn gbaná ní ẹkùn Maradi…

Anambra Decides: Ọ̀jọ̀gbọ́n Sólúdò jáwé olúborí ní ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́tà-dínlógún lábé…

Ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Grand Alliance, APGA, ti jáwé olúborí ní àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́tàdínlógún nínú àwọn ìpínlẹ̀ mọ́kàn-dínlógún gẹ́gẹ́ bíí àjọ elétò ìdìbò orílè-èdè (INEC) ṣe kéde nínú ìdìbò gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra.…

AnambraDecides:Ètò ìdìbò gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra forí ṣánpọ́n

Àjọ elétò ìdìbò olómìnira orílẹ̀-èdè (INEC) ti kéde  ìdìbò gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra ti ọdún 2021 pé ó forí ṣánpọ́n  nítorí pé  ìdìbò kò wáyé ní ìjọba ìbílẹ̀ Ihiala ní ìpínlẹ̀ náà. Oṣiṣẹ ajọ ọhun…

Anambra: Ẹgbẹ́ bẹnu àté lu bíí Àwọn abarapáá kò ṣe láǹfààní láti dìbò

Ẹgbẹ́ àwọn olùwòye ìdìbò ti bẹnu àtẹ́ lu bí  ìdá mẹ́rìnlé-láàdọ́ta nínú àwọn ọ̀nà tí ó lọ sí àwọn ààyè ìdìbò tí wọ́n ṣe àyẹ̀wò rẹ̀  fún Àwọn abara páá (PWDs) lákòókò ìdìbò gómìnà ní ọjọ…
button