Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn afẹ̀hónúhàn Sri Lanka Bèèrè Ìdájọ́ Fún ìkọlù Ọjọ́ àjíǹde Krísítì Ọdún 2019

Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Sri Lanka ń fi ẹ̀hónúhàn láti bíi  ọjọ́ díẹ̀ sẹ́yìn nítósí ọ́fíísì ààrẹ tí wọ́n sí ǹ bèèrè fún ìdájọ́ òdodo fún àwọn olùfaragbà ìkọlù aburú Ọjọ́ àjíǹde Kírísítì tí ó   …

Ìdìbò 2023: Àwọn olùdarí ẹ̀sìn rọ àwọn olóṣèlú Láti ní ẹ̀mí ìṣòdodo

Gẹ́gẹ́ bí ìdìbò Gbogboogbò ọdún 2023 Nàìjíríà ṣe ń bọ̀ lọ́nà, Àpéjọ Àwọn Bíṣọ́ọ́bù kátílííkì Nàìjíríà,CBCN, ti rọ àwọn olósèlú láti ní ẹ̀mí ìṣedédé. Aarẹ CBCN, Bishop Lucius Ugorji, ṣe ipe naa ninu…
button